Jeremáyà 33:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “‘Ní àwọn ìlú tó wà ní agbègbè olókè àti ní àwọn ìlú tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, ní àwọn ìlú tó wà ní gúúsù àti ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì, ní agbègbè Jerúsálẹ́mù+ àti ní àwọn ìlú Júdà,+ agbo ẹran yóò tún pa dà kọjá lábẹ́ ọwọ́ ẹni tó ń kà wọ́n,’ ni Jèhófà wí.”
13 “‘Ní àwọn ìlú tó wà ní agbègbè olókè àti ní àwọn ìlú tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, ní àwọn ìlú tó wà ní gúúsù àti ní ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì, ní agbègbè Jerúsálẹ́mù+ àti ní àwọn ìlú Júdà,+ agbo ẹran yóò tún pa dà kọjá lábẹ́ ọwọ́ ẹni tó ń kà wọ́n,’ ni Jèhófà wí.”