Ìdárò 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.
16 Nítorí nǹkan wọ̀nyí ni mo ṣe ń sunkún;+ omijé sì ń dà lójú mi. Nítorí ẹni tó lè tù mí nínú tàbí tó lè tù mí* lára ti jìnnà réré sí mi. Àwọn ọmọ mi kò nírètí, nítorí ọ̀tá ti borí.