Ìdárò 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jerúsálẹ́mù ti dá ẹ̀ṣẹ̀ tó pọ̀.+ Ìdí nìyẹn tó fi di ohun ìríra. Gbogbo àwọn tó ń bọlá fún un tẹ́lẹ̀ ti wá ń fojú ẹ̀gàn wò ó, nítorí wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀.+ Òun fúnra rẹ̀ kérora,+ ó sì yíjú pa dà pẹ̀lú ìtìjú.
8 Jerúsálẹ́mù ti dá ẹ̀ṣẹ̀ tó pọ̀.+ Ìdí nìyẹn tó fi di ohun ìríra. Gbogbo àwọn tó ń bọlá fún un tẹ́lẹ̀ ti wá ń fojú ẹ̀gàn wò ó, nítorí wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀.+ Òun fúnra rẹ̀ kérora,+ ó sì yíjú pa dà pẹ̀lú ìtìjú.