-
Ìsíkíẹ́lì 25:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí, ‘Torí ẹ pàtẹ́wọ́,+ tí ẹ fẹsẹ̀ kilẹ̀, tí ẹ* sì ń yọ̀ bí ẹ ṣe ń fi ilẹ̀ Ísírẹ́lì ṣe irú ẹlẹ́yà yìí,+ 7 torí náà, èmi yóò na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ yín, kí n lè mú kí àwọn orílẹ̀-èdè kó ẹrù yín lọ. Màá pa yín rẹ́ láàárín àwọn èèyàn, màá sì pa yín run ní àwọn ilẹ̀ náà.+ Màá pa yín rẹ́, ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’
-