Jeremáyà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.
17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.