ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 11:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Wò ó, màá pè wọ́n wá jíhìn. Idà ni yóò pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn,+ ìyàn sì ni yóò pa àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin wọn.+

  • Ìdárò 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Dìde! Bú sẹ́kún ní òru, ní ìbẹ̀rẹ̀ àkókò ìṣọ́.

      Tú ọkàn rẹ jáde bí omi níwájú Jèhófà.

      Gbé ọwọ́ rẹ sókè sí Ọlọ́run nítorí ẹ̀mí* àwọn ọmọ rẹ,

      Tó ń kú lọ nítorí ìyàn ní gbogbo oríta* ojú ọ̀nà.+

  • Ìdárò 4:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ahọ́n ọmọ ẹnu ọmú lẹ̀ mọ́ òkè ẹnu rẹ̀ nítorí òùngbẹ.

      Àwọn ọmọ tọrọ oúnjẹ,*+ àmọ́ kò sí ẹni tó fún wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́