Sáàmù 48:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ Ìsíkíẹ́lì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “‘Òkìkí rẹ bẹ̀rẹ̀ sí í kàn* láàárín àwọn orílẹ̀-èdè+ torí ẹwà rẹ, ẹwà rẹ kò lábùlà torí èmi ni mo dá ọ lọ́lá,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
14 “‘Òkìkí rẹ bẹ̀rẹ̀ sí í kàn* láàárín àwọn orílẹ̀-èdè+ torí ẹwà rẹ, ẹwà rẹ kò lábùlà torí èmi ni mo dá ọ lọ́lá,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”