-
Émọ́sì 8:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Màá sán aṣọ ọ̀fọ̀* mọ́ gbogbo ìbàdí, màá sì mú gbogbo orí pá;
Màá ṣe é bí ìgbà téèyàn ń ṣọ̀fọ̀ nítorí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo,
Màá sì mú kí ìgbẹ̀yìn rẹ̀ dà bí ọjọ́ tó korò.’
-