Ìsíkíẹ́lì 37:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àgọ́* mi yóò wà pẹ̀lú* wọn, èmi yóò di Ọlọ́run wọn, wọn yóò sì di èèyàn mi.+