Ọbadáyà 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìgbéraga* ọkàn rẹ ti tàn ọ́ jẹ,+Ìwọ tó ń gbé ihò inú àpáta,Ìwọ tó ń gbé ibi gíga, tí o sì ń sọ nínú ọkàn rẹ pé,‘Ta ló lè rẹ̀ mí wálẹ̀?’
3 Ìgbéraga* ọkàn rẹ ti tàn ọ́ jẹ,+Ìwọ tó ń gbé ihò inú àpáta,Ìwọ tó ń gbé ibi gíga, tí o sì ń sọ nínú ọkàn rẹ pé,‘Ta ló lè rẹ̀ mí wálẹ̀?’