Àìsáyà 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìdájọ́* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa gbé e ga,Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni Mímọ́,+ máa fi òdodo+ sọ ara rẹ̀ di mímọ́. Ìsíkíẹ́lì 20:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Òórùn dídùn* náà yóò mú kí inú mi dùn sí yín, nígbà tí mo bá mú yín jáde láàárín àwọn èèyàn, tí mo sì kó yín jọ láti àwọn ilẹ̀ tí ẹ fọ́n ká sí;+ màá sì fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín yín níṣojú àwọn orílẹ̀-èdè.’+
16 Ìdájọ́* Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa gbé e ga,Ọlọ́run tòótọ́, Ẹni Mímọ́,+ máa fi òdodo+ sọ ara rẹ̀ di mímọ́.
41 Òórùn dídùn* náà yóò mú kí inú mi dùn sí yín, nígbà tí mo bá mú yín jáde láàárín àwọn èèyàn, tí mo sì kó yín jọ láti àwọn ilẹ̀ tí ẹ fọ́n ká sí;+ màá sì fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ láàárín yín níṣojú àwọn orílẹ̀-èdè.’+