Ìsíkíẹ́lì 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá wó àwọn pẹpẹ yín, màá fọ́ àwọn ohun tí ẹ fi ń sun tùràrí,+ màá sì ju òkú àwọn èèyàn yín síwájú àwọn òrìṣà ẹ̀gbin yín.*+
4 Màá wó àwọn pẹpẹ yín, màá fọ́ àwọn ohun tí ẹ fi ń sun tùràrí,+ màá sì ju òkú àwọn èèyàn yín síwájú àwọn òrìṣà ẹ̀gbin yín.*+