Ìdárò 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+ Ìsíkíẹ́lì 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mi ò ní ṣàánú yín, mi ò sì ní yọ́nú sí yín,+ torí màá fi ìwà yín san yín lẹ́san. Ẹ ó jìyà gbogbo ohun ìríra tí ẹ ṣe.+ Ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’+
21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+
4 Mi ò ní ṣàánú yín, mi ò sì ní yọ́nú sí yín,+ torí màá fi ìwà yín san yín lẹ́san. Ẹ ó jìyà gbogbo ohun ìríra tí ẹ ṣe.+ Ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’+