Ìfihàn 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta àti ààbọ̀ náà, ẹ̀mí ìyè látọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọnú wọn,+ wọ́n dúró lórí ẹsẹ̀ wọn, ẹ̀rù sì ba àwọn tó rí wọn gidigidi.
11 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́ta àti ààbọ̀ náà, ẹ̀mí ìyè látọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọnú wọn,+ wọ́n dúró lórí ẹsẹ̀ wọn, ẹ̀rù sì ba àwọn tó rí wọn gidigidi.