Ìsíkíẹ́lì 27:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jáfánì, Túbálì+ àti Méṣékì+ bá ọ dòwò pọ̀, wọ́n sì fi àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà ṣe àti àwọn ẹrú+ ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ. Ìsíkíẹ́lì 32:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Ibẹ̀ ni Méṣékì àti Túbálì+ àti gbogbo èèyàn wọn* tó pọ̀ rẹpẹtẹ wà. Sàréè wọn* yí i ká. Aláìdádọ̀dọ́* ni gbogbo wọn, wọ́n fi idà gún wọn pa, torí wọ́n dẹ́rù bani ní ilẹ̀ alààyè.
13 Jáfánì, Túbálì+ àti Méṣékì+ bá ọ dòwò pọ̀, wọ́n sì fi àwọn ohun tí wọ́n fi bàbà ṣe àti àwọn ẹrú+ ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.
26 “‘Ibẹ̀ ni Méṣékì àti Túbálì+ àti gbogbo èèyàn wọn* tó pọ̀ rẹpẹtẹ wà. Sàréè wọn* yí i ká. Aláìdádọ̀dọ́* ni gbogbo wọn, wọ́n fi idà gún wọn pa, torí wọ́n dẹ́rù bani ní ilẹ̀ alààyè.