Àìsáyà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*Òkè ilé Jèhófà Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,+A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,Gbogbo orílẹ̀-èdè á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+
2 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*Òkè ilé Jèhófà Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,+A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,Gbogbo orílẹ̀-èdè á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+