-
Ìsíkíẹ́lì 40:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àgbàlá ìta ní ẹnubodè tó dojú kọ àríwá, ó sì wọn gígùn rẹ̀ àti fífẹ̀ rẹ̀. 21 Yàrá ẹ̀ṣọ́ mẹ́ta wà ní ẹ̀gbẹ́ kọ̀ọ̀kan. Ìwọ̀n àwọn òpó tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kọ̀ọ̀kan àti ibi àbáwọlé* rẹ̀ dọ́gba pẹ̀lú ìwọ̀n ẹnubodè àkọ́kọ́. Gígùn rẹ̀ jẹ́ àádọ́ta (50) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25).
-