ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìsíkíẹ́lì 41:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ilé tó wà ní ìwọ̀ oòrùn tó dojú kọ àyè fífẹ̀ náà jẹ́ àádọ́rin (70) ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀, gígùn rẹ̀ sì jẹ́ àádọ́rùn-ún (90) ìgbọ̀nwọ́; ìnípọn ògiri ilé náà yí ká jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún.

  • Ìsíkíẹ́lì 41:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ó wọn ilé tó kọjú sí ẹ̀yìn àyè fífẹ̀ náà, pẹ̀lú àwọn ọ̀dẹ̀dẹ̀ rẹ̀ ní ẹ̀gbẹ́ méjèèjì, gígùn rẹ̀ sì jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́.

      Ó tún wọn ibi mímọ́ ìta, ibi mímọ́ inú+ àti àwọn ibi àbáwọlé* ní àgbàlá náà,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́