Àìsáyà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.” Ìsíkíẹ́lì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ògo Jèhófà+ gbéra láti orí àwọn kérúbù wá sí ẹnu ọ̀nà ilé náà, ìkùukùu sì bẹ̀rẹ̀ sí í kún inú ilé náà díẹ̀díẹ̀,+ ògo Jèhófà sì mọ́lẹ̀ yòò ní gbogbo àgbàlá náà.
3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”
4 Ògo Jèhófà+ gbéra láti orí àwọn kérúbù wá sí ẹnu ọ̀nà ilé náà, ìkùukùu sì bẹ̀rẹ̀ sí í kún inú ilé náà díẹ̀díẹ̀,+ ògo Jèhófà sì mọ́lẹ̀ yòò ní gbogbo àgbàlá náà.