Ìsíkíẹ́lì 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tó mú mi dé ibẹ̀, mo rí ọkùnrin kan tí ìrísí rẹ̀ dà bíi bàbà.+ Ó mú okùn ọ̀gbọ̀ àti ọ̀pá esùsú* tí wọ́n fi ń wọn nǹkan dání,+ ó sì dúró ní ẹnubodè.
3 Nígbà tó mú mi dé ibẹ̀, mo rí ọkùnrin kan tí ìrísí rẹ̀ dà bíi bàbà.+ Ó mú okùn ọ̀gbọ̀ àti ọ̀pá esùsú* tí wọ́n fi ń wọn nǹkan dání,+ ó sì dúró ní ẹnubodè.