Àìsáyà 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ọdún tí Ọba Ùsáyà kú,+ mo rí Jèhófà tó jókòó sórí ìtẹ́ gíga, tó sì ta yọ,+ etí aṣọ rẹ̀ kún inú tẹ́ńpìlì. Jeremáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.” Ìsíkíẹ́lì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ohun tó rí bí òkúta sàfáyà+ wà lókè ohun tó tẹ́ pẹrẹsẹ lórí wọn, ó dà bí ìtẹ́.+ Ẹnì kan tó rí bí èèyàn sì jókòó sórí ìtẹ́ náà.+
6 Ní ọdún tí Ọba Ùsáyà kú,+ mo rí Jèhófà tó jókòó sórí ìtẹ́ gíga, tó sì ta yọ,+ etí aṣọ rẹ̀ kún inú tẹ́ńpìlì.
17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.”
26 Ohun tó rí bí òkúta sàfáyà+ wà lókè ohun tó tẹ́ pẹrẹsẹ lórí wọn, ó dà bí ìtẹ́.+ Ẹnì kan tó rí bí èèyàn sì jókòó sórí ìtẹ́ náà.+