Ìsíkíẹ́lì 16:63 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Nígbà tí mo bá dárí jì ọ́* láìka gbogbo ohun tí o ti ṣe sí,+ wàá rántí, ìtìjú ò sì ní jẹ́ kí o lè la ẹnu rẹ+ torí pé o ti tẹ́,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
63 Nígbà tí mo bá dárí jì ọ́* láìka gbogbo ohun tí o ti ṣe sí,+ wàá rántí, ìtìjú ò sì ní jẹ́ kí o lè la ẹnu rẹ+ torí pé o ti tẹ́,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”