-
Ẹ́kísódù 29:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Àmọ́ kí o fi iná sun ẹran akọ màlúù náà pẹ̀lú awọ rẹ̀ àti ìgbẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn òde àgọ́. Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.
-
-
Léfítíkù 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó wá fi iná sun ohun tó ṣẹ́ kù lára akọ màlúù náà, awọ rẹ̀, ẹran rẹ̀ àti ìgbẹ́ rẹ̀ ní ẹ̀yìn ibùdó+ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún un.
-