ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 “Kí o fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa hun aṣọ tó ní bátànì igun mẹ́rin, kí o sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní, kí o sì hun ọ̀já.+

  • Ẹ́kísódù 28:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Kí o tún fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe ṣòkòtò péńpé* fún wọn kó lè bo ìhòòhò wọn.+ Kó gùn láti ìbàdí dé itan.

  • Ẹ́kísódù 39:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe aṣọ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, ẹni tó ń hun aṣọ ló ṣe é,+ 28 wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa ṣe láwàní+ àti aṣọ tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ tí wọ́n máa wé sórí,+ wọ́n sì fi aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe àwọn ṣòkòtò péńpé,*+

  • Léfítíkù 16:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Kó wọ ẹ̀wù mímọ́ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀*+ ṣe, kó sì wọ ṣòkòtò péńpé*+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe láti bo ara* rẹ̀, kó de ọ̀já+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe mọ́ra, kó sì wé láwàní+ tí wọ́n fi aṣọ ọ̀gbọ̀ ṣe sórí. Aṣọ mímọ́+ ni wọ́n. Kó fi omi wẹ̀,+ kó sì wọ àwọn aṣọ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́