Léfítíkù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ò gbọ́dọ̀ mu wáìnì tàbí àwọn ohun mímu míì tó ní ọtí nígbà tí ẹ bá wá sínú àgọ́ ìpàdé,+ kí ẹ má bàa kú. Àṣẹ tí ìran yín á máa pa mọ́ títí láé ni.
9 “Ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ ò gbọ́dọ̀ mu wáìnì tàbí àwọn ohun mímu míì tó ní ọtí nígbà tí ẹ bá wá sínú àgọ́ ìpàdé,+ kí ẹ má bàa kú. Àṣẹ tí ìran yín á máa pa mọ́ títí láé ni.