Òwe 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Tí kò bá sí ẹran ọ̀sìn,* ibùjẹ ẹran á mọ́ tónítóní,Àmọ́ agbára akọ màlúù máa ń mú kí ìkórè pọ̀.