-
Ìsíkíẹ́lì 48:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bẹ̀rẹ̀ láti ààlà Júdà, láti ààlà tó wà ní ìlà oòrùn dé ààlà tó wà ní ìwọ̀ oòrùn, kí fífẹ̀ ilẹ̀ tí ẹ ó yà sọ́tọ̀ láti fi ṣe ọrẹ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́,*+ kí gígùn rẹ̀ sì dọ́gba pẹ̀lú ilẹ̀ àwọn ẹ̀yà yòókù láti ààlà tó wà ní ìlà oòrùn dé ààlà tó wà ní ìwọ̀ oòrùn. Àárín rẹ̀ ni ibi mímọ́ máa wà.
9 “Kí ilẹ̀ tí ẹ ó yà sọ́tọ̀ láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, kí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́.
-