Ìsíkíẹ́lì 40:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó wá mú mi wá sí àgbàlá ìta, mo sì rí àwọn yàrá ìjẹun*+ àti pèpéle tó yí àgbàlá náà ká. Ọgbọ̀n (30) yàrá ìjẹun ló wà lórí pèpéle náà.
17 Ó wá mú mi wá sí àgbàlá ìta, mo sì rí àwọn yàrá ìjẹun*+ àti pèpéle tó yí àgbàlá náà ká. Ọgbọ̀n (30) yàrá ìjẹun ló wà lórí pèpéle náà.