-
Léfítíkù 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Kó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé orí ẹran náà, ọrẹ rẹ̀ yóò sì ní ìtẹ́wọ́gbà, á sì jẹ́ ètùtù fún un.
-
-
Léfítíkù 6:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Àmọ́, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ti mú lára ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ wá sínú àgọ́ ìpàdé láti ṣe ètùtù ní ibi mímọ́.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun ún.
-