-
Ìsíkíẹ́lì 41:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Fífẹ̀ ẹnu ọ̀nà náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá, ògiri tó wà ní ẹ̀gbẹ́ ẹnu ọ̀nà náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní ẹ̀gbẹ́ kan àti ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní ẹ̀gbẹ́ kejì. Ó wọn gígùn rẹ̀, ó jẹ́ ogójì (40) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́.
-