48 “Orúkọ àwọn ẹ̀yà náà nìyí, bẹ̀rẹ̀ láti ìkángun àríwá: ìpín Dánì+ wà lẹ́bàá ọ̀nà Hẹ́tílónì lọ dé Lebo-hámátì+ dé Hasari-énánì, lẹ́bàá ààlà Damásíkù sí apá àríwá, lẹ́gbẹ̀ẹ́ Hámátì;+ ó bẹ̀rẹ̀ láti ààlà tó wà ní ìlà oòrùn títí dé ààlà tó wà ní ìwọ̀ oòrùn.