-
Ìsíkíẹ́lì 45:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “‘Ẹ ó ya apá kan sọ́tọ̀ tó máa jẹ́ ohun ìní tó jẹ́ ti ìlú. Gígùn rẹ̀ máa jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́, (èyí tó bá ilẹ̀ mímọ́ náà mu) fífẹ̀ rẹ̀ á sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ìgbọ̀nwọ́.+ Yóò jẹ́ ti gbogbo ilé Ísírẹ́lì.
-