Ìsíkíẹ́lì 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà àti iṣẹ́ ara wọn ń dán bí òkúta kírísóláítì, àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin sì jọra. Iṣẹ́ ara wọn àti bí wọ́n ṣe rí dà bí ìgbà tí àgbá kẹ̀kẹ́ kan wà nínú àgbá kẹ̀kẹ́ míì.*
16 Àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ náà àti iṣẹ́ ara wọn ń dán bí òkúta kírísóláítì, àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin sì jọra. Iṣẹ́ ara wọn àti bí wọ́n ṣe rí dà bí ìgbà tí àgbá kẹ̀kẹ́ kan wà nínú àgbá kẹ̀kẹ́ míì.*