ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 39:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ọba Bábílónì ní kí wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekáyà níṣojú rẹ̀ ní Ríbúlà, ọba Bábílónì sì ní kí wọ́n pa gbogbo èèyàn pàtàkì Júdà.+ 7 Lẹ́yìn náà, ó fọ́ ojú Sedekáyà, ó sì fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà dè é kó lè mú un wá sí Bábílónì.+

  • Jeremáyà 52:24-27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Olórí ẹ̀ṣọ́ tún mú Seráyà+ olórí àlùfáà àti Sefanáyà+ àlùfáà kejì pẹ̀lú àwọn aṣọ́nà mẹ́ta.+ 25 Ó mú òṣìṣẹ́ ààfin kan tó jẹ́ kọmíṣọ́nnà lórí àwọn ọmọ ogun láti inú ìlú náà àti àwọn ọkùnrin méje tó rí nínú ìlú náà tí wọ́n sún mọ́ ọba àti akọ̀wé olórí àwọn ọmọ ogun, tó máa ń pe àwọn èèyàn ilẹ̀ náà jọ àti ọgọ́ta (60) ọkùnrin lára àwọn èèyàn ilẹ̀ náà, tó tún rí nínú ìlú náà. 26 Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ mú wọn, ó sì kó wọn wá sọ́dọ̀ ọba Bábílónì ní Ríbúlà. 27 Ọba Bábílónì ṣá wọn balẹ̀, ó sì pa wọ́n ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì. Bí Júdà ṣe lọ sí ìgbèkùn láti ilẹ̀ rẹ̀ nìyẹn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́