Ẹ́kísódù 24:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà. 17 Lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ògo Jèhófà rí bí iná tó ń jẹ nǹkan run lórí òkè náà. Ìsíkíẹ́lì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì wà níbẹ̀,+ ó dà bí ohun tí mo rí ní pẹ̀tẹ́lẹ̀.+
16 Ògo Jèhófà+ ò kúrò lórí Òkè Sínáì,+ ìkùukùu náà sì bò ó fún ọjọ́ mẹ́fà. Ní ọjọ́ keje, ó pe Mósè látinú ìkùukùu náà. 17 Lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó ń wo ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ògo Jèhófà rí bí iná tó ń jẹ nǹkan run lórí òkè náà.