Dáníẹ́lì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó wá sọ fún mi pé: “Dáníẹ́lì, ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an,*+ fiyè sí ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ fún ọ. Ó yá, dìde níbi tí o wà, torí a ti rán mi sí ọ.” Nígbà tó sọ ọ̀rọ̀ yìí fún mi, mo dìde, mo bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n.
11 Ó wá sọ fún mi pé: “Dáníẹ́lì, ìwọ ọkùnrin tó ṣeyebíye gan-an,*+ fiyè sí ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ sọ fún ọ. Ó yá, dìde níbi tí o wà, torí a ti rán mi sí ọ.” Nígbà tó sọ ọ̀rọ̀ yìí fún mi, mo dìde, mo bẹ̀rẹ̀ sí í gbọ̀n.