Ẹ́kísódù 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+
2 “Ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí mímọ́* fún mi. Tèmi ni àkọ́bí yín lọ́kùnrin àti àkọ́bí ẹran yín tó jẹ́ akọ.”+