Àìsáyà 40:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ẹ sọ ọ̀rọ̀ tó máa wọ Jerúsálẹ́mù lọ́kàn,*Kí ẹ sì kéde fún un pé iṣẹ́ rẹ̀ tó pọn dandan ti parí,Pé a ti san gbèsè ẹ̀bi tó jẹ.+ Ó ti gba ohun tó kún rẹ́rẹ́* lọ́wọ́ Jèhófà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.”+
2 “Ẹ sọ ọ̀rọ̀ tó máa wọ Jerúsálẹ́mù lọ́kàn,*Kí ẹ sì kéde fún un pé iṣẹ́ rẹ̀ tó pọn dandan ti parí,Pé a ti san gbèsè ẹ̀bi tó jẹ.+ Ó ti gba ohun tó kún rẹ́rẹ́* lọ́wọ́ Jèhófà fún gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.”+