Jeremáyà 2:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ǹjẹ́ wúńdíá lè gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,Àbí ìyàwó lè gbàgbé ọ̀já ìgbàyà* rẹ̀? Síbẹ̀, àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi tipẹ́tipẹ́.+
32 Ǹjẹ́ wúńdíá lè gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,Àbí ìyàwó lè gbàgbé ọ̀já ìgbàyà* rẹ̀? Síbẹ̀, àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi tipẹ́tipẹ́.+