-
Diutarónómì 20:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ṣe ni kí o pa wọ́n run pátápátá, ìyẹn àwọn ọmọ Hétì, àwọn Ámórì, àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn Pérísì, àwọn Hífì àti àwọn ará Jébúsì,+ bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe pa á láṣẹ fún ọ gẹ́lẹ́;
-
-
Jóṣúà 10:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ni àwọn ọba Ámórì+ márààrún bá kóra jọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn, ìyẹn ọba Jerúsálẹ́mù, ọba Hébúrónì, ọba Jámútì, ọba Lákíṣì àti ọba Ẹ́gílónì, wọ́n sì lọ pàgọ́ ti Gíbíónì láti bá a jà.
-