Ìsíkíẹ́lì 20:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Ibẹ̀ ni ẹ ó sì ti rántí gbogbo ìwà àti ìṣe yín tí ẹ fi sọ ara yín di aláìmọ́,+ ẹ ó sì kórìíra ara* yín nítorí gbogbo ohun búburú tí ẹ ṣe.+
43 Ibẹ̀ ni ẹ ó sì ti rántí gbogbo ìwà àti ìṣe yín tí ẹ fi sọ ara yín di aláìmọ́,+ ẹ ó sì kórìíra ara* yín nítorí gbogbo ohun búburú tí ẹ ṣe.+