Jeremáyà 22:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ̀yin tó ń gbé ní Lẹ́bánónì,+Tí ìtẹ́ yín wà láàárín igi kédárì,+Ẹ wo bí ẹ ó ti kérora tó nígbà tí ìrora bá dé bá yín,Ìdààmú* bíi ti obìnrin tó ń rọbí!”+
23 Ẹ̀yin tó ń gbé ní Lẹ́bánónì,+Tí ìtẹ́ yín wà láàárín igi kédárì,+Ẹ wo bí ẹ ó ti kérora tó nígbà tí ìrora bá dé bá yín,Ìdààmú* bíi ti obìnrin tó ń rọbí!”+