-
Ìsíkíẹ́lì 20:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 “‘Bí mo ṣe dá àwọn baba ńlá yín lẹ́jọ́ nínú aginjù ilẹ̀ Íjíbítì, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe dá yín lẹ́jọ́,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
-