Ìsíkíẹ́lì 33:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Èmi kò ní ka èyíkéyìí nínú ẹ̀ṣẹ̀ tó ti dá sí i lọ́rùn.*+ Ó dájú pé yóò máa wà láàyè torí ó ṣe ohun tó tọ́, ó sì ṣe òdodo.’+
16 Èmi kò ní ka èyíkéyìí nínú ẹ̀ṣẹ̀ tó ti dá sí i lọ́rùn.*+ Ó dájú pé yóò máa wà láàyè torí ó ṣe ohun tó tọ́, ó sì ṣe òdodo.’+