Jóṣúà 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń tì wọ́n kúrò níwájú yín, ó lé wọn kúrò* fún yín,+ ẹ sì gba ilẹ̀ wọn, bí Jèhófà Ọlọ́run yín ti ṣèlérí fún yín gẹ́lẹ́.+
5 Jèhófà Ọlọ́run yín ló ń tì wọ́n kúrò níwájú yín, ó lé wọn kúrò* fún yín,+ ẹ sì gba ilẹ̀ wọn, bí Jèhófà Ọlọ́run yín ti ṣèlérí fún yín gẹ́lẹ́.+