Àìsáyà 50:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.+ Ìdí nìyẹn tí ìtìjú ò fi ní bá mi. Ìdí nìyẹn tí mo fi ṣe ojú mi bí akọ òkúta,+Mo sì mọ̀ pé ojú ò ní tì mí.
7 Àmọ́ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.+ Ìdí nìyẹn tí ìtìjú ò fi ní bá mi. Ìdí nìyẹn tí mo fi ṣe ojú mi bí akọ òkúta,+Mo sì mọ̀ pé ojú ò ní tì mí.