Ìsíkíẹ́lì 16:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 “‘Ẹ̀ṣẹ̀ Samáríà+ kò tiẹ̀ tó ìdajì tìrẹ. Ṣe ni ohun ìríra tí ò ń ṣe ń pọ̀ sí i, débi pé gbogbo ohun ìríra tí ò ń ṣe mú kí àwọn arábìnrin rẹ dà bí olódodo.+
51 “‘Ẹ̀ṣẹ̀ Samáríà+ kò tiẹ̀ tó ìdajì tìrẹ. Ṣe ni ohun ìríra tí ò ń ṣe ń pọ̀ sí i, débi pé gbogbo ohun ìríra tí ò ń ṣe mú kí àwọn arábìnrin rẹ dà bí olódodo.+