Diutarónómì 27:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá fojú kéré bàbá àti ìyá rẹ̀.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)