ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 22:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 “Tí ẹ bá yá ìkankan nínú àwọn èèyàn mi tó jẹ́ aláìní* lówó, ẹni tó ń bá yín gbé, ẹ ò gbọ́dọ̀ hùwà sí i bí àwọn tó ń yáni lówó èlé.* Ẹ ò gbọ́dọ̀ gba èlé lọ́wọ́ rẹ̀.+

  • Léfítíkù 6:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Tó bá ti ṣẹ̀, tó sì jẹ̀bi, kó dá ohun tó jí pa dà àti ohun tó fipá gbà, ohun tó fi jìbìtì gbà, ohun tí wọ́n fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ tàbí ohun tó sọ nù tí ó rí, 5 tàbí ohunkóhun tó búra èké lé lórí, kó sì san gbogbo rẹ̀ pa dà,+ kó tún fi ìdá márùn-ún rẹ̀ kún un. Kó fún ẹni tó ni ín lọ́jọ́ tí wọ́n bá fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ó jẹ̀bi.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́