-
Ìsíkíẹ́lì 21:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Tí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló dé tí o fi ń mí kanlẹ̀?’ kí o sọ pé, ‘Torí ìròyìn kan ni.’ Torí ó dájú pé ó máa dé, ìbẹ̀rù á sì mú kí gbogbo ọkàn domi, gbogbo ọwọ́ yóò rọ jọwọrọ, ìrẹ̀wẹ̀sì yóò bá gbogbo ẹ̀mí, omi á sì máa ro tótó ní gbogbo orúnkún.*+ ‘Wò ó! Ó dájú pé ó máa dé, ó máa ṣẹlẹ̀,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-